Ọ̀rúnmìlà (Ifá)
Ọ̀rúnmìlà Bara Àgbọnnìrègún
Ọlọ́jà láàrin Ẹbọra
Aráyé rọ́run
Ẹlẹ́rìí Ìpín
Ajẹ́ ju oògùn
Atórí ẹni tí ò suhàn ṣe
Òdùdù tí du orí ìlémèrè kó má baà fọ́
Atóóbá jayé má jayà lolo
Ọ̀rúnmìlà Bara Àgbọnnìrègún,
Chief among the Divinities.
One who sees happenings on earth and in the heaven.
Witness to the act of chosing destiny.
He who is more effective than medicine.
He who repairs bad heads.
He who gives longevity to Emèrè.
One with whom one enjoys life without trepidation.